Eshu, p. 1

CONTENTS

Eshu Rezos

REZO 1. Bara su wayo (very short version)
_______

Eshu Opening & Ritual Songs

— songs 1, 2 and 6-9 still in progress
— SONG 1. Mojuba Orisha, mojuba o
— SONG 2. Eleggua (a)’go, e mojuba Elegguara
SONG 3. Iba Orisha, Iba laye o
SONG 4. Iba Orisha ma wo, alaroye joko de (calling roads of Eshu)
SONG 5. Eshu o, Elegbarra e
— SONG 6. Ibara (a)’go mojuba
— SONG 7. Son son abe, son son abe Odara
— SONG 8. Abukenke, abukenke
— SONG 9. Bara obebe tirriri lona, Eshu tirriri
_______

Eshu & Olokun Closing Songs

CLOSING 1. Bembe ko l’ashe Eleggba
CLOSING 2. Elegba nita laroye so ku o & Olokun gba wa o

__________

Eshu Rezos

REZO 1. Bara su wayo (a very short version)

A/C: Bara su wayo, omo yalawanna mama kenia irawo e (2x) O Bara su wayo, e ke, Eshu Odara, omo yalawanna mama kenia irawo e

__________

Eshu Songs

SONG 1. Mojuba Orisha, mojuba o (In this song, Akpon introduces song by singing both parts (1x); then continues singing only her part.)
A: Mojuba Orisha, mojuba o, mojuba Orisha
C: Ashe, mojuba Orisha
A: Mojuba o, mojuba Orisha
C: Ashe, mojuba Orisha

SONG 2. Eleggua (a)’go, e mojuba Elegguara
A/C: Eleggua ‘go, e mojuba Elegguara (2x) Bara lo yuo, ago Elegguara
_______

SONG 3. Iba Orisha, iba laye o

A/C: Iba Orisha, iba laye o, ashe mojuba
A/C: Iba Orisha, iba laye o, ago mojuba

SONG 4. Iba Orisha ma wo, alaroye joko de ( This song calls roads of Eshu: Odara, Alawanna, Alaroye, Opin, Oro, Elegba, Alaketu, etc.)
A: Iba Orisha ma wo, alaroye joko de (2x) Alaroye joko de Eshu ____________ joko de, Iba Orisha ma wo alaroye joko de.
C: Iba Orisha ma wo alaroye joko de.

SONG 5. Eshu o, Elegbarra e

A/C: Eshu o, Elegbarra e (2x) Elegbarra moforibale, Eleggbara (a)’go

__________

in progress
SONG 6. Ibara (a)’go mojuba
SONG 7. Son son abe, son son abe Odara
SONG 8. Abukenke, abukenke
SONG 9. Bara obebe tirriri lona, Eshu tirriri

__________

Eshu & Olokun, Closing Songs

CLOSING 1. Bembe ko l’ashe Eleggba

A: Eleggba, ‘legba, Eleggba ‘legba o, Bembe ko l’ashe Eleggba ( Akpon introduces song by singing both parts.)
C: Bembe ko l’ashe Eleggba

A: Eleggba, ‘legba, Eleggba ‘legba o
C: Bembe ko l’ashe Eleggba

A/C: Bembe ko l’ashe Eleggba

CLOSING 2. Elegba nita laroye so ku o and Olokun gba wa o

A: Elégbá ni (o)’ta (A)’lároyé s’(e) okú o
C: E Elégbá ni’ta ’lároyé s’okú o ayé

A/C: Àgò Elégbá e
A/C: Èsú Baba mi
A/C: Awa la temu e
A/C: A feji so fi e
A/C: Ìyá Olóòkun e
A/C: Ìyá (O)’re (I)’fá e

A: Olóòkun gbà wa o
C: Gbà wa Òrìsà, gbà wa o ààyè

A: Olóòkun Bàbá o
C: Bàbá Orisà, Bàbá o ayé

A: Olóòkun gbà wa o
C: Omi so olà gbà wa o ààyè